Rashida Adamu Abdullah
Rashida Adamu Abdullah, ti gbogbo eniyan mọ si Rashida Maisa'a. Jẹ́ òṣèré sinimá, olùgbéjáde sinimá, àti olóṣèlú ọmọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà; wọ́n bí i, wọ́n sì tọ́ dàgbà ní Tarauni, ní Ìpínlẹ̀ Kano, ní àríwá-ìwọ̀-oòrùn Nàìjíríà.[1] Rashida gbajúmọ̀ ní ilé iṣẹ́ fíìmù kannywood, fíìmù àkọ́kọ́ rẹ̀ ni Jariya, ṣùgbọ́n ó kọ́kọ́ ṣe fíìmù "Sa'a" èyí tí òun fúnra rẹ̀ gbé jáde, ó sì tún fún un ní orúkọ "Maisa'a". [2]
Fíìmù àwòrán
àtúnṣe- Tutar so
- Halwa
- Gobe-Da-Nisa
- Àkójọ àwọn òṣèré Nàìjíríà
- Àkójọ àwọn olùgbéré fíìmù ní Nàìjíríà
- Àkójọ àwọn òṣèré Kannywood
Àwọn ìtọ́kasí
àtúnṣePage Àdàkọ:Reflist/styles.css has no content.